Yorùbá Bibeli

1. Kro 27:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joabu ọmọ Seruiah bẹ̀rẹ si ikà wọn, ṣugbọn kò kà wọn tan, nitori ibinu ṣubu lu Israeli nitori na; bẹ̃ni a kò fi iye na sinu iwe Kronika ti Dafidi ọba.

1. Kro 27

1. Kro 27:18-28