Yorùbá Bibeli

1. Kro 26:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ninu awọn wọnyi ni ipin awọn adena, ani ninu awọn olori ọkunrin, ti nwọn ni iṣẹ gẹgẹ bi awọn arakunrin wọn, lati ṣe iranṣẹ ni ile Oluwa.

1. Kro 26

1. Kro 26:5-19