Yorùbá Bibeli

1. Kro 25:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

PẸLUPẸLU Dafidi ati awọn olori ogun yà ninu awọn ọmọkunrin Asafu, ati Hemani, ati Jedutuni, fun ìsin yi, awọn ẹniti o ma fi duru ati psalteri, ati kimbali kọrin: ati iye awọn oniṣẹ gẹgẹ bi ìsin wọn jẹ:

1. Kro 25

1. Kro 25:1-7