Yorùbá Bibeli

1. Kro 24:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li a fi iṣẹkeké pin wọn, iru kan mọ ikeji pẹlu; nitori awọn olori ibi mimọ́, ati olori ti Ọlọrun wà ninu awọn ọmọ Eleasari, ati ninu awọn ọmọ Itamari.

1. Kro 24

1. Kro 24:3-11