Yorùbá Bibeli

1. Kro 23:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lati ru gbogbo ẹbọ ọrẹ sisun fun Oluwa li ọjọjọ isimi, ati li oṣù titun ati li ọjọ wọnni ti a pa li aṣẹ, ni iye, li ẹsẹsẹ gẹgẹ bi aṣẹ ti a pa fun wọn nigbagbogbo niwaju Oluwa:

1. Kro 23

1. Kro 23:28-32