Yorùbá Bibeli

1. Kro 23:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi ni awọn ọmọ Lefi, bi ile baba wọn; ani olori awọn baba, bi a ti ka wọn ni iye orukọ, nipa ori wọn, awọn ti o ṣiṣẹ ìsin ile Oluwa, lati iwọn ogun ọdun ati jù bẹ̃ lọ.

1. Kro 23

1. Kro 23:20-32