Yorùbá Bibeli

1. Kro 20:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si kó awọn enia ti o wà nibẹ jade wá, o si fi ayùn ati irin mimu ati ãke ké wọn. Aní bayi ni Dafidi ṣe si gbogbo ilu awọn ọmọ Ammoni. Ati Dafidi ati gbogbo awọn enia pada bọ̀ si Jerusalemu.

1. Kro 20

1. Kro 20:1-5