Yorùbá Bibeli

1. Kro 2:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Geṣuri, ati Aramu, gbà ilu Jairi lọwọ wọn, pẹlu Kenati, ati ilu rẹ̀: ani ọgọta ilu. Gbogbo wọnyi ni awọn ọmọ Makiri baba Gileadi.

1. Kro 2

1. Kro 2:20-29