Yorùbá Bibeli

1. Kro 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn arabinrin wọn ni Seruiah ati Abigaili. Ati awọn ọmọ Seruiah; Abiṣai, ati Joabu, ati Asaeli, mẹta.

1. Kro 2

1. Kro 2:12-23