Yorùbá Bibeli

1. Kro 18:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ara Siria ti Damasku wá lati ran Hadareseri ọba Soba lọwọ, Dafidi pa ẹgbã mọkanla enia ninu awọn ara Siria.

1. Kro 18

1. Kro 18:2-12