Yorùbá Bibeli

1. Kro 16:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu wọn Hemani ati Jedutuni pẹlu ipè ati kimbali fun awọn ti yio ma pariwo, ati pẹlu ohun èlo orin Ọlọrun. Awọn ọmọ Jedutuni li awọn adena.

1. Kro 16

1. Kro 16:32-43