Yorùbá Bibeli

1. Kro 15:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Dafidi wipe, Ẹnikan kò yẹ lati rù apoti ẹri Ọlọrun bikoṣe awọn ọmọ Lefi; nitori awọn ni Oluwa ti yàn lati ma gbé apoti ẹri Ọlọrun, ati lati ma ṣe iranṣẹ fun u titi lai.

1. Kro 15

1. Kro 15:1-6