Yorùbá Bibeli

1. Kro 14:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn ara Filistia si gbọ́ pe, a fi ororo yan Dafidi li ọba lori gbogbo Israeli, gbogbo awọn ara Filistia gòke lọ iwá Dafidi: Dafidi si gbọ́, o si jade tọ̀ wọn.

1. Kro 14

1. Kro 14:1-15