Yorùbá Bibeli

1. Kro 13:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Dafidi ati gbogbo Israeli fi gbogbo agbara wọn ṣire niwaju Ọlọrun, pẹlu orin, ati pẹlu duru, ati pẹlu psalteri, ati pẹlu timbreli, ati pẹlu simbali, ati pẹlu ipè.

1. Kro 13

1. Kro 13:1-13