Yorùbá Bibeli

1. Kro 12:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati li apa keji odò Jordani, ninu ti awọn ọmọ Reubeni, ati awọn ọmọ Gadi, ati abọ ẹya Manasse, pẹlu gbogbo onirũru ohun elo ogun fun ogun ọ̀kọ, ọkẹ mẹfa.

1. Kro 12

1. Kro 12:27-40