Yorùbá Bibeli

1. Kro 12:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni iye awọn enia na ti o hamọra tan fun ogun, ti nwọn si tọ̀ Dafidi wá si Hebroni, lati pa ijọba Saulu da si ọdọ rẹ̀ gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa.

1. Kro 12

1. Kro 12:21-31