Yorùbá Bibeli

1. Kro 12:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Wọnyi li awọn ti o gòke odò Jordani li oṣù ekini, nigbati o kún bò gbogbo bèbe rẹ̀; nwọn si le gbogbo awọn ti o wà li afonifoji ninu ila-õrùn, ati niha iwọ-õrùn.

1. Kro 12

1. Kro 12:10-22