Yorùbá Bibeli

1. Kro 12:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

WỌNYI si li awọn ti o tọ̀ Dafidi wá si Siklagi, nigbati o fi ara rẹ̀ pamọ, nitori Saulu ọmọ Kiṣi: awọn wọnyi si wà ninu awọn akọni ti nṣe oluranlọwọ ogun na.

1. Kro 12

1. Kro 12:1-9