Yorùbá Bibeli

1. Kro 11:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni gbogbo awọn agbagba Israeli ṣe tọ ọba wá ni Hebroni; Dafidi si ba wọn da majẹmu ni Hebroni niwaju Oluwa; nwọn si fi ororo yan Dafidi li ọba lori Israeli, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa nipa ọwọ Samueli.

1. Kro 11

1. Kro 11:1-12