Yorùbá Bibeli

1. Kro 11:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn mẹta na si la inu ogun awọn ara Filistia kọja, nwọn si fa omi jade lati inu kanga Betlehemu, lati ẹnu-bodè, nwọn gbé e, nwọn si mu u tọ̀ Dafidi wá: Dafidi kò si fẹ mu u, ṣugbọn o tu u silẹ fun Oluwa,

1. Kro 11

1. Kro 11:14-20