Yorùbá Bibeli

1. Kro 1:26-30 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Serugu, Nahori, Tera,

27. Abramu; on na ni Abrahamu,

28. Awọn ọmọ Abrahamu; Isaaki, ati Iṣmaeli.

29. Wọnyi ni iran wọn: akọbi Iṣmaeli, Nebaioti; ati Kedari, ati Adbeeli, ati Mibsamu,

30. Miṣma, ati Duma, Massa, Hadadi, ati Tema,