Yorùbá Bibeli

1. Kor 5:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn kì iṣe pẹlu awọn àgbere aiye yi patapata, tabi pẹlu awọn olojukòkoro, tabi awọn alọnilọwọgbà, tabi awọn abọriṣa; nitori nigbana ẹ kò le ṣaima ti aiye kuro.

1. Kor 5

1. Kor 5:2-13