Yorùbá Bibeli

1. Kor 16:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn niti Apollo arakunrin wa, mo bẹ ẹ pupọ ki o tọ̀ nyin wá pẹlu awọn arakunrin: ṣugbọn kì iṣe ifẹ rẹ̀ rara lati wá nisisiyi; ṣugbọn on o wá nigbati o ba ni akokò ti o wọ̀.

1. Kor 16

1. Kor 16:5-22