Yorùbá Bibeli

1. Kor 11:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ, ará, mo yìn nyin ti ẹnyin nranti mi ninu ohun gbogbo, ti ẹnyin ti di ẹ̀kọ́ wọnni mu ṣinṣin, ani gẹgẹ bi mo ti fi wọn le nyin lọwọ.

1. Kor 11

1. Kor 11:1-5