Yorùbá Bibeli

1. Kor 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ninu ọgbọ́n Ọlọrun niwọnbi aiye kò ti mọ̀ nitori ọgbọ́n, o wù Ọlọrun nipa wère iwasu lati gbà awọn ti o gbagbọ́ là.

1. Kor 1

1. Kor 1:17-31