Yorùbá Bibeli

1. Kor 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si ijọ enia Ọlọrun ti o wà ni Korinti, awọn ti a sọ di mimọ́ ninu Kristi Jesu, awọn ẹniti a npè li enia mimọ́, pẹlu gbogbo awọn ti npè orukọ Jesu Kristi Oluwa wa nibigbogbo, ẹniti iṣe tiwọn ati tiwa:

1. Kor 1

1. Kor 1:1-8