Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 9:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni emi o ké Israeli kuro ni ilẹ ti emi fi fun wọn; ati ile yi, ti mo ti yà si mimọ́ fun orukọ mi li emi o gbe sọnù kuro niwaju mi; Israeli yio si di owe ati ifiṣẹsin lãrin gbogbo orilẹ-ède.

1. A. Ọba 9

1. A. Ọba 9:1-8