Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 9:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun u pe, Mo ti gbọ́ adura rẹ ati ẹ̀bẹ rẹ, ti iwọ ti bẹ̀ niwaju mi, mo ti ya ile yi si mimọ́, ti iwọ ti kọ́, lati fi orukọ mi sibẹ titi lai; ati oju mi ati ọkàn mi yio wà nibẹ titi lai.

1. A. Ọba 9

1. A. Ọba 9:1-10