Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 9:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Hiramu, ọba Tire ti ba Solomoni wá igi kedari ati igi firi, ati wura gẹgẹ bi gbogbo ifẹ rẹ̀, nigbana ni Solomoni ọba fun Hiramu ni ogún ilu ni ilẹ Galili.

1. A. Ọba 9

1. A. Ọba 9:3-16