Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:63 Yorùbá Bibeli (YCE)

Solomoni si ru ẹbọ ọrẹ-alafia, ti o ru si Oluwa, ẹgbã-mọkanla malu, ati ọkẹ mẹfa àgutan. Bẹ̃ni ọba ati gbogbo awọn ọmọ Israeli yà ile Oluwa si mimọ́.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:56-66