Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti nwọn o gbọ́ orukọ nla rẹ, ati ọwọ́ agbára rẹ, ati ninà apa rẹ; nigbati on o wá, ti yio si gbadura si iha ile yi;

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:38-45