Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki o gbọ́ li ọrun, ki o si dari ẹ̀ṣẹ Israeli, enia rẹ jì, ki o si mu wọn pada wá si ilẹ ti iwọ ti fi fun awọn baba wọn.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:30-43