Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 8:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si tẹtisilẹ si ẹ̀bẹ iranṣẹ rẹ ati ti Israeli, enia rẹ, ti nwọn o gbadura siha ibi yi: ki o si gbọ́ li ọrun, ibugbe rẹ! gbọ́, ki o si darijì.

1. A. Ọba 8

1. A. Ọba 8:22-40