Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ mọ̀ bi Dafidi, baba mi, kò ti le kọ́ ile fun orukọ Oluwa Ọlọrun rẹ̀ nitori ogun ti o wà yi i ka kiri, titi Oluwa fi fi wọn sabẹ atẹlẹsẹ rẹ̀.

1. A. Ọba 5

1. A. Ọba 5:1-8