Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 4:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si fun Solomoni li ọgbọ́n ati oye li ọ̀pọlọpọ, ati oye gbigboro, gẹgẹ bi iyanrin ti o wà leti okun.

1. A. Ọba 4

1. A. Ọba 4:19-30