Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 4:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Juda ati Israeli ngbe li alafia, olukuluku labẹ àjara rẹ̀ ati labẹ igi ọpọtọ́ rẹ̀, lati Dani titi de Beerṣeba, ni gbogbo ọjọ Solomoni.

1. A. Ọba 4

1. A. Ọba 4:19-28