Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 3:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba si lọ si Gibeoni lati rubọ nibẹ; nitori ibẹ ni ibi-giga nlanla: ẹgbẹrun ọrẹ ẹbọ-sisun ni Solomoni ru lori pẹpẹ na.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:1-14