Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 3:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Obinrin keji si wipe, Bẹ̃kọ; ṣugbọn eyi alãye ni ọmọ mi, eyi okú li ọmọ rẹ, eyi si wipe, Bẹ̃kọ; ṣugbọn eyi okú li ọmọ rẹ, eyi alãye si li ọmọ mi. Bayi ni nwọn nsọ niwaju ọba.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:19-24