Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 3:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ọjọ kẹta lẹhin igbati mo bimọ tan, obinrin yi si bimọ pẹlu: awa si jumọ ngbé pọ: kò si si alejo pẹlu wa ni ile bikoṣe awa mejeji ni ile.

1. A. Ọba 3

1. A. Ọba 3:15-24