Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:51 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahasiah, ọmọ Ahabu, bẹ̀rẹ si ijọba lori Israeli ni Samaria li ọdun kẹtadilogun Jehoṣafati, ọba Juda, o si jọba li ọdun meji lori Israeli.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:42-53