Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si rin ni gbogbo ọ̀na Asa baba rẹ̀; kò yipada kuro ninu rẹ̀, o nṣe eyiti o tọ li oju Oluwa: kiki a kò mu awọn ibi giga kuro; awọn enia si nrú ẹbọ, nwọn si nsun turari sibẹ̀ ni ibi giga wọnni.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:40-48