Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin kan si fà ọrun rẹ̀ laipete, o si ta ọba Israeli lãrin ipade ẹwu-irin; nitorina li o ṣe wi fun olutọju-kẹkẹ́ rẹ̀ pe, Yi ọwọ́ rẹ dà, ki o si mu mi jade kuro ninu ogun; nitoriti emi gbọgbẹ.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:27-40