Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 22:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn woli si nsọtẹlẹ bẹ̃ wipe: Goke lọ si Ramoti-Gileadi, ki o si ṣe rere: nitoriti Oluwa yio fi i le ọba lọwọ.

1. A. Ọba 22

1. A. Ọba 22:8-20