Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jesebeli, aya rẹ̀ si wi fun u pe, iwọ kò ha jọba lori Israeli nisisiyi? Dide, jẹun, ki o si jẹ ki inu rẹ ki o dùn! emi o fun ọ ni ọgba-àjara Nãboti ara Jesreeli.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:5-17