Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Ahabu gbọ́ ọ̀rọ wọnyi, o si fa aṣọ rẹ̀ ya, o si fi aṣọ ọ̀fọ si ara rẹ̀, o si gbàwẹ, o si dubulẹ ninu aṣọ ọ̀fọ, o si nlọ jẹ́.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:25-29