Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu si wi fun Elijah pe, Iwọ ri mi, Iwọ ọta mi? O si dahùn wipe, Emi ri ọ; nitoriti iwọ ti tà ara rẹ lati ṣiṣẹ buburu niwaju Oluwa.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:11-29