Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ahabu si ba Naboti sọ wipe, Fun mi ni ọgba-ajara rẹ, ki emi ki o fi ṣe ọgba-ewebẹ̀, nitori ti o sunmọ ile mi: emi o si fun ọ li ọgba-ajara ti o san jù u lọ dipò rẹ̀; bi o ba si dara li oju rẹ, emi o fi iye-owo rẹ̀ fun ọ.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:1-4