Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati Ahabu gbọ́ pe, Naboti kú, ni Ahabu dide lati sọkalẹ lọ si ọgba-ajara Naboti, ara Jesreeli lati jogun rẹ̀.

1. A. Ọba 21

1. A. Ọba 21:9-22