Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọkunrin kan ninu awọn ọmọ awọn woli si wi fun ẹnikeji rẹ̀ nipa ọ̀rọ Oluwa pe, Jọ̃, lù mi. Ọkunrin na si kọ̀ lati lù u.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:25-43