Yorùbá Bibeli

1. A. Ọba 20:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọkunrin na si ṣe akiyesi gidigidi, nwọn si yara gbá ohun ti o ti ọdọ rẹ̀ wá mu: nwọn si wipe, Benhadadi arakunrin rẹ! Nigbana li o wipe, Ẹ lọ mu u wá. Nigbana ni Benhadadi jade tọ̀ ọ wá; o si mu u goke wá sinu kẹkẹ́.

1. A. Ọba 20

1. A. Ọba 20:30-35